Bọ́lẹ̀kájà (2) láti ọwọ́ Ayọ̀ AdamsNí ọdún 2019, ilé elérò kan báyìí ni mò ń gbé ni Ayẹ́yẹ́. Oríṣiríṣi ìran ni àwa sì ma ń rí wò ní ibẹ̀. Ṣé ti àwọn ará ilé wa ni ká wí ní…Dec 19, 2021Dec 19, 2021
Bọ́lẹ̀kájà láti ọwọ́ Ayọ̀ AdamsẸnu iṣẹ́ ni mo wà ní Olúyọ̀lé ní ọ̀sán ọjọ́ ajé. Sàdédé ni ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ mí dún. Àwọn ìwé tí mò ń tó kò jẹ́ kí n kọ ara sí…Nov 6, 2021Nov 6, 2021
Awakọ̀ (The Driver): A City through the Eyes of a Taxi DriverAwakọ̀ (The driver), a series in development chronicles the experience of Lákúnlé, a Micra driver in the city of Ìbàdàn, as he navigates…Oct 19, 2021Oct 19, 2021
Àbíkú láti Ọwọ́ Ayo Adams“Ṣe o ti jí?” Bàbá bèrè bí o ti tẹ’jú mọ́ ìyá tó wa ọmọ náà mọ́ àyà. Bí ó ti ń gbé ọmọ náà sí orí ibùsùn, ìyá ni, “Koko lara ọtá le, kòsí…Sep 23, 2021Sep 23, 2021
Ìyàwó Yín – láti ọwọ́ Ayọ̀ AdamsẸ yámi ni ìyàwó yín Orun ọjọ́ kan ní ó sùn lọ́dọ̀ mi Ṣe mo le rí ìyàwó yín? Ọ̀rọ̀ pàtàkì kán wà tí mo fẹ́ bá a sọ Ní gbangba ní kọ̀rọ̀ À…Sep 15, 2021Sep 15, 2021
Ta ló kú? (Who died?) — A poem by Ayọ̀ AdamsTa ló kú? Ọmọ ẹnìkan kọ́ o Ẹ̀dùn ọkàn mi ló gun òkè nla kan lọ tó jábọ́Jul 4, 2021Jul 4, 2021
Akínyẹlé Ọmọ Jìnádù — láti ọwọ́ Ayọ̀ AdamsÀjò ò dùn títí, kí èrò oko mọ́ padà sí ilé. A dífá fún ọmọ Jìnádù tó lọ ìgboro èkó tó bọ̀. Àwọn tí wọ́n mọ̀ ọ́ ọmọkùnrin tí à ń ròyìn yìí…Feb 9, 20211Feb 9, 20211
Oko Ikún — láti ọwọ́ Ayọ̀ Adams (Ep. 1)Ísíákà ti ọwọ́ bọ àpò rẹ̀, ó mú ṣìnáàbù jáde, o ń dà gọ̀rọ̀gọ̀ sí ọ̀nà ọ̀fun. “Sé ìwọ ò ní wá nkan jẹ ni? Àbí ó di ìgbà tí wọ́n bá wá gbé…Feb 6, 2021Feb 6, 2021
Ajínigbé láti ọwọ́ Ayọ̀ Adams (Final)Nígbà tí Láàní padà wọlé, o sàlàyé nkan to ṣẹlẹ̀ bí Àyìndé àti ọmọ ti wọlé dé. “Mo se bàlàbàlà múra, mo sì se bálabàla sáré wọ yàrá…Dec 24, 2020Dec 24, 2020
Ajínigbé láti ọwọ́ Ayọ̀ Adams — (Ep. 7)Nígbà tí Èyíwùmí parí gbogbo rọ̀bọ̀rebe lórí ago tó sì sálàyé pé ọkọ̀ òun n bọ́ ni ilé fúnmi. Àfira, mo ni ki n palẹ̀mọ́ ara kí n le jápa…Dec 22, 20201Dec 22, 20201